Kolose 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjìnlẹ̀ àṣírí nìyí, ó ti wà ní ìpamọ́ láti ìgbà àtijọ́ ati láti ìrandíran, ṣugbọn Ọlọrun fihan àwọn eniyan rẹ̀ ní àkókò yìí.

Kolose 1

Kolose 1:24-29