Joṣua 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli wí fún àwọn ará Hifi náà pé, “Bóyá nítòsí ibí ni ẹ ti wá, báwo ni a ṣe lè ba yín dá majẹmu?”

Joṣua 9

Joṣua 9:1-16