Joṣua 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n wọ sálúbàtà tí ó ti gbó ati aṣọ àkísà, gbogbo oúnjẹ tí wọn mú lọ́wọ́ ni ó ti gbẹ, tí ó sì ti bu.

Joṣua 9

Joṣua 9:4-10