Joṣua 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí a lè ṣe ni pé kí á dá wọn sí, kí ibinu OLUWA má baà wá sórí wa, nítorí ìbúra tí a ti ṣe fún wọn.”

Joṣua 9

Joṣua 9:12-27