Joṣua 8:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àfi ẹran ọ̀sìn ati dúkìá ìlú náà ni àwọn ọmọ Israẹli kó ní ìkógun gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Joṣua.

Joṣua 8

Joṣua 8:17-35