Joṣua 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nǹkan bí ẹgbẹẹdogun (3,000) ninu àwọn ọmọ Israẹli lọ gbógun tì wọ́n. Ṣugbọn wọ́n sá níwájú àwọn ará Ai.

Joṣua 7

Joṣua 7:1-12