Joṣua 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ máa tẹ̀síwájú, ẹ rìn yípo ìlú náà kí àwọn ọmọ ogun ṣáájú Àpótí Majẹmu OLUWA.”

Joṣua 6

Joṣua 6:1-14