Joṣua 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn gbogbo fadaka ati wúrà ati àwọn ohun èlò idẹ ati ti irin jẹ́ ohun ìyàsọ́tọ̀ fún OLUWA, inú ilé ìṣúra OLUWA ni a óo kó wọn sí.”

Joṣua 6

Joṣua 6:18-21