Joṣua 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA wí fún Joṣua pé, “Fi akọ òkúta ṣe abẹ, kí o sì fi kọ ilà abẹ́ lẹẹkeji fún àwọn ọmọ Israẹli.”

Joṣua 5

Joṣua 5:1-9