Joṣua 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan bíi ọ̀kẹ́ meji (40,000) ọkunrin tí wọ́n ti múra ogun, ni wọ́n rékọjá níwájú OLUWA lọ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹriko.

Joṣua 4

Joṣua 4:10-18