Joṣua 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni àwọn eniyan náà gbéra ninu àgọ́ wọn láti la odò Jọdani kọjá pẹlu àwọn alufaa tí wọn ń gbé Àpótí Majẹmu lọ níwájú wọn,

Joṣua 3

Joṣua 3:13-17