Joṣua 24:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rán Mose ati Aaroni sí wọn ní ilẹ̀ Ijipti, mo fi àjàkálẹ̀ àrùn bá àwọn ará Ijipti jà, lẹ́yìn náà mo ko yín jáde.

Joṣua 24

Joṣua 24:1-15