Joṣua 24:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Eleasari, ọmọ Aaroni kú; wọ́n sì sin ín sí Gibea, ìlú Finehasi, ọmọ rẹ̀, tí ó wà ní agbègbè olókè Efuraimu.

Joṣua 24

Joṣua 24:24-33