Joṣua 24:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá sin ín sórí ilẹ̀ rẹ̀ ní Timnati Sera, tí ó wà ní agbègbè olókè Efuraimu, ní apá ìhà àríwá Gaaṣi.

Joṣua 24

Joṣua 24:25-33