Joṣua 24:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí ara yín, pé OLUWA ni ẹ yàn láti máa sìn.”Wọ́n dáhùn pé, “Àwa ni ẹlẹ́rìí.”

Joṣua 24

Joṣua 24:13-29