Joṣua 24:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe idà tabi ọfà ni ẹ fi ṣẹgun àwọn ọba ará Amori mejeeji, agbọ́n ni mo rán ṣáájú yín tí ó sì lé wọn jáde fun yín.

Joṣua 24

Joṣua 24:11-14