Joṣua 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ̀yin náà ti rí ohun tí OLUWA Ọlọrun yín ti ṣe sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi nítorí yín, ati pé OLUWA Ọlọrun yín ni ó jà fun yín.

Joṣua 23

Joṣua 23:1-11