Joṣua 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

ó wí fún wọn pé, “Gbogbo ohun tí Mose, iranṣẹ OLUWA pa láṣẹ fun yín ni ẹ ti ṣe; ẹ sì ti ṣe gbogbo ohun tí èmi náà pa láṣẹ fun yín.

Joṣua 22

Joṣua 22:1-8