Joṣua 21:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo ìlérí dáradára tí OLUWA ṣe fún ilé Israẹli kò sí èyí tí kò mú ṣẹ; gbogbo wọn patapata ni ó mú ṣẹ.

Joṣua 21

Joṣua 21:43-45