Joṣua 21:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìlú mẹtala ati pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn ni ilẹ̀ tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Geriṣoni, gẹ́gẹ́ bi iye ìdílé wọn.

Joṣua 21

Joṣua 21:30-42