Joṣua 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìlú àwọn ọmọ Kohati yòókù jẹ́ mẹ́wàá pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn.

Joṣua 21

Joṣua 21:18-34