Joṣua 21:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ilẹ̀ ẹ̀yà Dani, wọ́n fún wọn ní àwọn ìlú wọnyi pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn: Eliteke, Gibetoni.

Joṣua 21

Joṣua 21:13-32