Joṣua 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti inú ilẹ̀ ẹ̀yà Efuraimu ni wọ́n ti gba ìlú fún àwọn ọmọ Kohati yòókù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà Lefi.

Joṣua 21

Joṣua 21:17-23