Joṣua 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó ti kó wọn gun orí òrùlé rẹ̀, ó sì ti fi wọ́n pamọ́ sáàrin pòpórò igi ọ̀gbọ̀ tí ó tò jọ sibẹ.

Joṣua 2

Joṣua 2:1-11