Joṣua 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin meji náà sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, wọ́n lọ bá Joṣua, ọmọ Nuni, wọ́n bá sọ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wọn fún un.

Joṣua 2

Joṣua 2:19-24