Joṣua 19:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ààlà ilẹ̀ náà bẹ̀rẹ̀ ní Helefi, láti ibi igi oaku tí ó wà ní Saananimu, Adaminekebu, ati Jabineeli, títí dé Lakumu, ó sì pin sí odò Jọdani.

Joṣua 19

Joṣua 19:28-37