Joṣua 19:3-7 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Hasari Ṣuali, Bala, Esemu;

4. Elitoladi, Betuli, Horima,

5. Sikilagi, Beti Makabotu, ati Hasari Susa;

6. Beti Lebaotu ati Ṣaruheni, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹtala.

7. Enrimoni, Eteri, ati Aṣani, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹrin,

Joṣua 19