Joṣua 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ààlà ilẹ̀ náà lọ kan Tabori, Ṣahasuma ati Beti Ṣemeṣi, kí ó tó lọ pin sí odò Jọdani. Gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹrindinlogun.

Joṣua 19

Joṣua 19:14-29