Joṣua 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti Saridi, ààlà ilẹ̀ náà lọ sí òdìkejì, ní ìhà ìlà oòrùn, títí dé ààlà Kisiloti Tabori, láti ibẹ̀, ó lọ sí Daberati títí lọ sí Jafia;

Joṣua 19

Joṣua 19:10-17