Joṣua 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ kẹta tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Sebuluni. Agbègbè tí ó jẹ́ ìpín tiwọn lọ títí dé Saridi.

Joṣua 19

Joṣua 19:8-19