Joṣua 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ keji tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Simeoni, ilẹ̀ tiwọn bọ́ sí ààrin ìpín ti ẹ̀yà Juda.

Joṣua 19

Joṣua 19:1-4