Joṣua 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo ṣe àkọsílẹ̀ ìpín mejeeje, ẹ óo sì mú un tọ̀ mí wá. N óo ba yín ṣẹ́ gègé lórí wọn níhìn-ín, níwájú OLUWA Ọlọrun wa.

Joṣua 18

Joṣua 18:1-15