Joṣua 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Israẹli ti ṣẹgun ilẹ̀ náà, gbogbo wọn péjọ sí Ṣilo, wọ́n sì pa àgọ́ àjọ níbẹ̀.

Joṣua 18

Joṣua 18:1-5