Joṣua 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli di alágbára, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi tipátipá mú àwọn ará Kenaani sìn, wọn kò sì lé wọn jáde patapata.

Joṣua 17

Joṣua 17:11-18