Joṣua 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ní ìsàlẹ̀, láti Janoa, lọ sí Atarotu ati Naara. Ó lọ títí dé Jẹriko, ó sì pin sí odò Jọdani.

Joṣua 16

Joṣua 16:1-10