Joṣua 15:49-53 BIBELI MIMỌ (BM)

49. Jatiri, Soko, Dana, Kiriati Seferi (tí à ń pè ní Debiri),

50. Anabu, Eṣitemoa, Animi,

51. Goṣeni, Holoni, ati Gilo; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkanla.

52. Arabu, Duma, Eṣani, Janimu,

53. Beti Tapua, Afeka, Humita,

Joṣua 15