Joṣua 15:48-52 BIBELI MIMỌ (BM)

48. Àwọn ìlú tí wọ́n wà ní orí òkè nìwọ̀nyí: Ṣamiri,

49. Jatiri, Soko, Dana, Kiriati Seferi (tí à ń pè ní Debiri),

50. Anabu, Eṣitemoa, Animi,

51. Goṣeni, Holoni, ati Gilo; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkanla.

52. Arabu, Duma, Eṣani, Janimu,

Joṣua 15