Joṣua 15:40-43 BIBELI MIMỌ (BM)

40. Lahimami, Kitiliṣi; Gederotu;

41. Beti Dagoni, Naama, ati Makeda; gbogbo ìlú ati ìletò wọ́n jẹ́ mẹrindinlogun.

42. Libina, Eteri, Aṣani, Ifita;

43. Aṣinai, Nesibu, Keila;

Joṣua 15