Joṣua 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó lọ títí dé Asimoni, ó tọ ipa odò Ijipti, ó sì pin sí Òkun Mẹditarenia. Òun ni yóo jẹ́ ààlà ilẹ̀ Juda ní apá ìhà gúsù.

Joṣua 15

Joṣua 15:1-6