36. Ṣaaraimu, Aditaimu, Gedera, Gederotaimu; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹrinla.
37. Senani, Hadaṣa, Migidaligadi,
38. Dileani, Misipa, Jokiteeli,
39. Lakiṣi, Bosikati, Egiloni, Kaboni;
40. Lahimami, Kitiliṣi; Gederotu;
41. Beti Dagoni, Naama, ati Makeda; gbogbo ìlú ati ìletò wọ́n jẹ́ mẹrindinlogun.
42. Libina, Eteri, Aṣani, Ifita;
43. Aṣinai, Nesibu, Keila;
44. Akisibu, ati Mareṣa; gbogbo ìlú ati ìletò wọ́n jẹ́ mẹsan-an.
45. Ekironi pẹlu àwọn ìlú ati ìletò rẹ̀;
46. láti Ekironi títí dé etí òkun Mẹditarenia, ati gbogbo àwọn ìlú tí wọ́n wà lẹ́bàá Aṣidodu pẹlu àwọn ìletò wọn.