Joṣua 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Otinieli ọmọ Kenasi, arakunrin Kalebu, ni ó ṣẹgun ìlú náà. Kalebu bá fi Akisa ọmọ rẹ̀ fún un láti fi ṣe aya.

Joṣua 15

Joṣua 15:10-19