Joṣua 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkun yìí ni ààlà ilẹ̀ náà ní apá ìwọ̀ oòrùn.Òun ni ààlà ilẹ̀ àwọn ọmọ Juda gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.

Joṣua 15

Joṣua 15:10-19