Joṣua 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé Mose ti fún àwọn ẹ̀yà meji ati ààbọ̀ ní ìpín tiwọn ní òdìkejì odò Jọdani, ṣugbọn kò pín ilẹ̀ fún àwọn ẹ̀yà Lefi.

Joṣua 14

Joṣua 14:1-10