Joṣua 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

láti Aroeri tí ó wà ní etí àfonífojì Arinoni ati ìlú tí ó wà ní ààrin gbùngbùn àfonífojì náà, ati ilẹ̀ tí ó tẹ́jú ní Medeba títí dé Diboni;

Joṣua 13

Joṣua 13:2-19