Joṣua 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Mose kò pín ilẹ̀ fún àwọn ẹ̀yà Lefi, OLUWA Ọlọrun Israẹli ni ìpín tiwọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti wí fún wọn.

Joṣua 13

Joṣua 13:24-33