Joṣua 13:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ tiwọn ni Jaseri ati gbogbo ìlú Gileadi, ati ìdajì ilẹ̀ àwọn ará Amoni, títí dé Aroeri tí ó wà ní ìlà oòrùn Raba;

Joṣua 13

Joṣua 13:19-26