Joṣua 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí, Joṣua ti di àgbàlagbà, ogbó sì ti dé sí i. OLUWA bá sọ fún un pé, “Ogbó ti dé sí ọ, ṣugbọn ilẹ̀ pupọ ni ó kù láti gbà.

Joṣua 13

Joṣua 13:1-4