Joṣua 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣẹgun Ogu, ọba Baṣani náà. Ogu yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn tí ó kù ninu ìran Refaimu tí ń gbé Aṣitarotu ati Edirei.

Joṣua 12

Joṣua 12:1-9