Joṣua 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọba wọnyi parapọ̀, wọ́n kó gbogbo ọmọ ogun wọn jọ láti bá Israẹli jagun. Wọ́n sì pàgọ́ sí etí odò Meromu.

Joṣua 11

Joṣua 11:1-15