Joṣua 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ wá ràn mí lọ́wọ́. Ẹ jẹ́ kí á kọlu Gibeoni, nítorí pé ó ti bá Joṣua ati àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu alaafia.”

Joṣua 10

Joṣua 10:3-10